Congregational Hymn Mayokun 32 “Tire
titi lai lawa nse” by A. T. Ola Olude
1. Tire titi lai, l’awa ‘se
Oluwa wa orun,
Tire l’omode, tire l’agba,
‘W’ Olorun Ife o:
Di
wa mu, Oba Iye (2)
Si jek’a yin ‘fe Re,
K’ ohun at’ iwa wa k’o j’okan,
Amin, be ni k’o ri.
2. Tire titi lai, l’awa ‘se
Balogun wa orun
Pelu wa n’b’ ere at’ oju-‘ja,
K’a ma se te s’ Ibi.
3. tire l’ojo t’ Idamu mbe
Oluwa wa orun;
Tire nigb’ ekun ati l’ayo
Olorun ajito.
4. Tire l’ojo t’ ireti mbe,
T’a nri je, t’o nye wa;
Tire b’ebi de ati n’nu ‘ya,
Olorun ‘tunu yi.
5. Tire titi lai, yan fun ‘ni
Alase wa orun;
Tire l’enu ‘se ati l’ero,
Olorun Isegun.
6. Tire l’ojo t’aisan bam be
T’a nsu won l’agbole;
Tire bi Iku npe wa s’ Orun,
Olorun aiku yi.
14. Hymns in Choir procession
(a)
EMHB 668 – Tune : Angel voices
(b)
EMHB 431 – Tune : Blanwern
(c)
EMHB 942 – Tune : Abends (second tune) Re-dedication of the Choir
PRESENTATION
II
15. Festival Hymn EMHB 5 “Let all the world
in every corner sing” – Tune : Luckington
16. Festival Anthem : “Yi ye l’odo agutan” by
Ayo Oluranti – Choir only
17. Festival Dance : (a) “I danced in the morning” – (Tune : Lord of
the Dance) – Choir
Adesegun Akitoye
http://www.homebusinessassurance.com
No comments:
Post a Comment