1. PSALM 121
(Celebrant: Verses 1-2)
1. I lift up my eyes to
the hills where
does my help come from?
2. My help comes from
the Lord, the
Maker of heaven and earth.
(Congregation
Verses 3-end)
3. He will not let your
foot slip he who
watches over you will not slumber;
4. Indeed, he who
watches over Israel
will neither slumber nor sleep.
5. The Lord watches over
you, the
Lord is your shade at your right
hand;
6. The sun will not harm
you by day,
nor the moon by night.
7. The Lord will keep
you from all
harm he will watch over your life;
8. The Lord will watch
over your
coming and going both now and
forever more.
ORIN
DAFIDI 121
(Olojo Ibi: Ese Kinni ati Ikeji)
1. Emi o gbe oju mi si
ori oke wonni,
nibo ni iranlowo mi yio ti nwa?
2. Iranlowo mi yio ti
owo Oluwa wa,
ti o da orun on aiye.
(Gbogbo
Ijo: Ese Keta titi de Ipari)
3. On ki yio je ki ese
re ki o ye; eniti
npa o mo ki yio togbe.
4. Kiyesi I, eniti npa
Israeli mo, ki
itogbe, beni ki isun.
5. Oluwa li Olupamo re:
Oluwa li ojiji
re li owo otun re.
6. Orun ki yio pa o
nigba osan, tabi
osupa nigba oru.
7. Oluwa yio pa o mo
kuro ninu ibi
gbogbo : yio pa okan re mo.
8. Oluwa yio pa alo ati
abo re mo lati
igba yi lo, ati titi lailai.
Adesegun Akitoye
http://www.spiritualhymnsong.blogspot.com
No comments:
Post a Comment