11.
Recessional Hymn Akokun 22 “B’o ba ni Jesu k’o dimu”
- B’o ba ni Jesu k’o dimu,
K’o si toro
imuduro,
Jesu, Oluwa
mi,
Mu mi duro
dopin.
Mu mi duro, mu mi duro,
Mu mi duro dopin,
Jesu, Oluwa mi,
Mu mi duro dopin.
- Ninu ofi-ola aiye,
Pelu danwo
arotele,
Jesu, Oluwa
mi,
Mu mi duro
dopin.
- Nigba ‘banuje ile
B’a d’ori okan
mi kodo;
Jesu, Oluwa
mi,
Mu mi duro
dopin.
- Nigba wahal’ aiye l’otun
Idanwo Esu li
osi,
Jesu, Oluwa
mi,
Mu mi duro
dopin.
- Nigba Esu gbe mi soke,
T’o fe k’emi
k’o teriba,
Jesu, Oluwa
mi,
Mu mi duro
dopin.
- Nigbat’ o ku emi nikan,
Ti ko si
alabaro mo;
Jesu, Oluwa
mi,
Mu mi duro
dopin.
Adesegun Akitoye
http://www.homebusinessassurance.com
Wonderful Methodist Hymmn...thanks for posting it here.
ReplyDelete