11.
Carol Mayokun “Irawo didan kan yo”
- Irawo didan kan yo (2)
Ni ila-orun si
awon amoye,
Irawo t’o po
l’ogo ni.
Egbe: Irawo yi pe l’ogo, o pe,
Irawo yi pe l’ogo, o fi Jesu han
Pe Oba iyanu ni, egan ko si nipa Re.
- Irawo yi kede Re (2)
O si fi eso to
awon amoye
T’ on ajo de
‘bugbe Oba.
Egbe: Etan ko si n’nu won ke, ranti,
Etan ko si n’nu won ke, nwon to Jesu
Pel’ ore won eyi t’o je ebun ife
lat’ okan.
- Irawo yi n’ ifihan (2)
Fun t’ ewe t’
agba ti o tele la ni,
Irawo yi ki
tan’ ni
Egbe: Irawo yi l’ajuwe pipe
Irawo yi l’ajuwe , lati to opo d’ odo
Jesu
Oba won; Irawo yi jeri Re.
- Irawo yi mu won yo (2)
L’ayo yi tara,
nwon si pada lo
Se ‘rohin kale
de ‘lu won
Egbe: Edun l’eyi fun Herodu, Oba
Ko si le te e mora ke, o jowu gb’ese
Lo ‘p’ omo agbo won je,
Ko si mo pe Jesu ye.
Adesegun Akitoye
http://www.homebusinessassurance.com
No comments:
Post a Comment