Choir Rendition II
i.
Obangiji awa tun de
Obangiji awa tun de
Pelu iyin,
Fun ore Re igba gbogbo
A wa sope, Baba rere;
Wa gba ‘yin gb’ ope wa.
Edumare, gb’ ope wa;
Oyigiyigi
a de o, dakun
Gb’ ebe wa.
ii.
Or’ elese, re wa lekun
B’a
ti njosin,
Gbo
‘gbe omo Re, Baba Mimo,
A
nfe ‘Soji at’ Iwosan;
K’
ifiji Re je tiwa
Edumare,
k’o je tiwa;
Oyigiyigi,
etc.
iii.
Tu wa lara, Emi Mmo,
Gbe
wa n’ Ija;
Jek’
a so eso iwa rere,
Busi
‘gbagbo gbogbo wa;
K’
iwasu sise ‘re
Edumare,
jek’ o se ‘re;
Oyigiyigi,
etc.
iv.
Bukun fun wa Baba Mimo,
Olu-ayo;
K’
Ijoba Re tete k’ aiye
L’a
nfe julo, Baba rere;
K’a
f’ ayo re ‘le wa
Edumare,
tebi t’omo;
Oyigiyigi,
etc.
Adesegun Akitoye
http://www.homebusinessassurance.com
No comments:
Post a Comment