i.
Oyigiyigi Lolorun Wa
Oyigiyigi
Lolorun wa o o o
Oyigiyigi
oba aiku
Iwo ma
lope iyin ye fun o
E wole
josin folorun wa o o o
O ba ni o
Oyigiyigi
ni o
Oyigiyigi
ni seeeeee
ii.
E fope foba wa mimo - by Sammy
Adeusi
i.
E fope fun, Oba wa mimo o
E fope
fun, Oba wa mimo o
Tori anu
re, Lori wa se
E fope
fun, Oba wa mimo o
ii.
E fiyin fun, Oba wa mimo ni
Egbe e ga,
Oba to joba lo
Mukulu Mukeke
E fope
fun, Oba wa mimo o
iii.
E fogo foba mimo o
Oun nikan
lo le gba ni
E fogo fun
se a dupe
E fope
fun, Oba wa mimo o.
Adesegun Akitoye
http://www.homebusinessassurance.com
No comments:
Post a Comment