Saturday, February 22, 2014

Take Home Anthem : Oluwa, Iwo lo ti nse ibujoko wa



16.  Cutting of Choir President Birthday Cake / Take Home Anthem – Oluwa, iwo lo ti nse ibujoko wa

Oluwa, Iwo lo ti nse ibujoko wa
Lati iran di ran
Ogo ogo fun o, Alleluia alleluia
Kia to bi awon oke nla, Iwo ni olorun
Oba wa, Oluwa iwo lo ti nse ibujoko wa
Lati iran di ran
Apata ayeraye, Eni ti mbe lailai o
Nigba kigba ti ji ja, Iwo ni a ala fi a
Sa ju di da aye, ni iwo ti wa,
Titi a ye ainipekun
Ayeraye, aye raye o ni o
Alpha Omega, Alpha Omega
Oluwa Iwo lo ti nse ibujoko wa
Lati iran di ran
Olorun odun to ko ja
Alpha Omega ni oooo


Adesegun Akitoye
http://www.homebusinessassurance.com

No comments:

Post a Comment

Roll Call of Members Alphabets T, W, X, Y & Z at 2024 Family Reunion Thanksgiving at Wesley Cathedral Olowogbowo

Alphabets T, W, X, Y, Z The N. A. B. Thomas Family The Adeoye Thomas Family The Kemi Thomas Family The Strack/Tay Family The B. K. Tandoh Fa...