1. PROCESSIONAL HYMN – YMHB 9
1. Okan mi, yin Oba
orun,
M’ ore re wa s’ odo Re,
’Wo t’a wosan t’a dariji,
Tal’ o ba ha yin bi Re?
Yin Oluwa,
Yin Oba ainipekun.
2. Yin fun anu Re si
awon
Baba wa, n’nu ‘ponju won;
Yin I, okanna ni titi,
O lora lati binu;
Yin Oluwa,
Ologo n’nu otito.
3. Bi baba li O ntoju
wa,
O si mo ailera wa;
Jeje l’ O ngbe wa l’ apa Re,
O ngba wa lowo ota;
Yin Oluwa,
Anu Re yi aiye ka.
4. Enyin angel’, e juba
Re;
Enyin nri lojukoju;
Orun, osupa, e wole,
Ati gbogbo agbaiye,
E ba wa yin
Olorun Olor’-ofe.
2. CALL TO WORSHIP
3. INTROIT – E SEUN OLUWA
4. EXTEMPORAL PRAYERS AND THE LORD’S PRAYER
5. HIGH PRAISES IN WORSHIP
Adesegun Akitoye
http://spiritualhymnsong.blogspot.com
No comments:
Post a Comment