1. (a) The Old
Testament – Psalm 65:9-13 (Band)
(b) The Hymn YMHB 769 (Collection for Evangelism)
1. Ojo ibukun yio ro :
Eyi n’ ileri ife;
Akoko itura y’o de
Lat’ odo Olugbala.
Ojo ibukun,
Ojo ibukun l’a nfe;
Iri anu nse yi wa ka,
Sugbon ojo l’a ntoro.
2. Ojo ibukun yio ro :
Ohun gbogbo y’o soji,
Lori oke on petele
Iro opo ojo mbo,
Ojo ibukun, etc.
3. Ojo ibukun yio ro :
Ran won si wa Oluwa!
Fun wa n’ itura nisiyi
Wa, bola fun oro Re.
Ojo ibukun, etc.
4. Ojo ibukun yio ro :
Iba je le ro loni,
B’a ti njewo fun Olorun,
Ti a si nkepe Jesu.
Ojo ibukun, etc.
(c) The Gospel Lesson – Matthew 13:24-30, 36-43
Adesegun Akitoye
http://spiritualhymnsong.blogspot.com
No comments:
Post a Comment