Friday, April 24, 2020
TAL' AWON WONYI B' IRAWO
10. HOMILY IWAAASU
11. CREED AND INTERCESSORY PRAYER IJEWO IGBAGBO ATI ADURA MIRAN
12. GENERAL THANKSGIVING IDUPE GBOGBOGBO
(All Carded Offerings)
13. ACT OF REMEMBRANCE ETO SISE IRANTI
a. Moment of Silence Wiwa ni Idakeje
b. Hymn : Who are these saint Orin YMHB 621
1. Tal’ awon wonyi b’ irawo,
Niwaju ‘te Olorun?
Gbogbo nwon de ade wura,
Egbe ogo wo l’ eyi?
Gbo! Nwon nko, Alleluya,
Nwon nf’ iyin fun Oba won.
2. Tali awon ti nko mona,
T’a wo l’ aso ododo:
Awon ti aso funfun won,
Y’o wa ni mimo titi,
Ti ki o si gbo lailai?
Nibo l’ egbe yi ti wa?
3. Awon wonyi l’o ti jagun,
F’ ola Olugbala won,
Nwon ja titi d’ oju iku,
Nwon ko k’ egbe elese;
Awon ni ko sa f’ ogun,
Nwon segun nipa Kristi.
4. Awon yi l’ okan won gbogbe,
Ninu ‘danwo kikoro,
Awon l’o ti fi adura
B’ Olorun jijakadi;
‘Rora ija won pari,
Olorun re won l’ ekun.
5. Awon wonyi l’o ti sona,
Nwon f’ ife won fun Kristi,
Nwon si ya ‘ra won si mimo,
Lati sin nigbagbogbo;
Nisisiyi li orun,
Nwon wa l’ ayo l’ odo Re.
c. Prayers for the saints and faithful Adura fun awon Obi ti o ti
Departed parents ku ninu Oluwa
d. Prayers for the families of Adura fun awon Ebi awon
the faithful departed parents Oloogbe
14. FAMILY REUNION THANKSGIVING IDUPE MOLEBI
15. OTHER THANKSGIVING IDUPE MIRAN
16. NOTICES IFILO
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Roll Call of Members Alphabets T, W, X, Y & Z at 2024 Family Reunion Thanksgiving at Wesley Cathedral Olowogbowo
Alphabets T, W, X, Y, Z The N. A. B. Thomas Family The Adeoye Thomas Family The Kemi Thomas Family The Strack/Tay Family The B. K. Tandoh Fa...
-
The Christmas is here again. Let us enjoy the Order of Nine Lessons and Carols as organized by the Wesley Guild, Wesley Cathedral Olowogbowo...
-
1. PSALM 121 (Celebrant: Verses 1-2) 1. I lift up my eyes to the hills where does my help come from? 2. My help...
-
INTERMENT SENTENCES AT THE GRAVE SIDE As a father pities his children, so the Lord pities those who fear him. For he knows our f...
No comments:
Post a Comment