Friday, April 24, 2020

O ALL YE WORKS OF THE LORD / GBOGBO ENYIN ISE OLUWA

4. PRAYER AND THE LORD’S PRAYER ADURA ATI ADURA OLUWA 5. PRAISE AND WORSHIP ORIN IYIN ATI OPE (Cathedral Maintenance Fund) 6. COLLECT KOLETI 7. BIBLE READING BIBELI KIKA a. O.T. : Malachi 3:1-4 Majemu Lailai : Malaki 3:1-4 b. N.T. : Philipp. 1:3-11 Majemu Titun : Filipi 1:3-11 c. Canticle : All Ye Works Orin YMHB 848 Benedicte, Omnia Opera “All ye works of the Lord” 1. O All ye works of the Lord / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 2. O ye angels of the Lord, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 3. O ye heavens, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 4. O ye sun, moon and stars, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 5. O ye winter and summer, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 6. O ye nights and days, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 7. O let the earth / bless the / Lord: Yea, let it / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 8. O ye seas and floods, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 9. O all ye that move in the waters, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 10. O ye fowls of the air, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 11. O ye beasts and cattle, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 12. O ye children of men, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 13. O ye servants of the Lord, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 14. O ye souls of the righteous, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. 15. O ye holy and humble men of heart, / bless ye the / Lord: / Praise Him, and / magnify / Him for / ever. GLORIA. ORIN YMHB 848 Gbogbo enyin Ise Oluwa, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Angeli Oluwa, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Orun, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Omi ti o wa loke Ofurufu, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Gbogbo enyin Ipa Oluwa, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Orun ati Osupa, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Irawo oju Orun, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Ojo ati Iri, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Efufu Olorun, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Ina ati Oru, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Ojo ati Erun, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Iri didi, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Iri didi ati Otutu, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Omi didi ati Yinyin, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Osan ati Oru, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Imole ati Okunkun, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Manamana ati Samma orun-sisu, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Ki Aiye fi ibukun fun Oluwa : ani ki o yin, ki o si ma gbe ga titi lai. Enyin Oke nla ati Oke kekeke, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Gbogbo enyin Eweko Tutu lori Ile, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Kanga, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Okun ati Isan omi, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Erinmi, ati gbogbo ohun elemi ninu Omi, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Gbogbo enyin Eiye oju Orun, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Gbogbo enyin Eranko ati ohun Osin, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Omo Enia, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Ki Israeli fi ibukun fun Oluwa, ki o yin, ki o si ma gbe ga titi lai. Enyin Alufa Oluwa, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Iranse Oluwa, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Emi ati Okan awon Olododo, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Enyin Enia mimo ati onirele okan, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Anania, Asaria, Misaeli, e fi ibukun fun Oluwa : e yin, ki si ma gbe ga titi lai. Ogo ni fun Baba, ati fun Omo, ati fun Emi Mimo; Bi o ti wa li atetekose, o mbe nisisiyi, beni yio si ma ri nigbagbogbo, aiye ainipekun. Amin.

No comments:

Post a Comment

COMMITTAL / FOR AS SUCH AS YOUR SERVANT, MRS. VICTORIA OLAMIDE WILLIAMS DEPARTED

COMMITTAL   We know that if the earthly house of our tabernacle be dissolved, we have a building from God, a house not made with hands, ...