Wednesday, May 6, 2020

B' ELESE SO 'WO PO / ONJE ORUN, MA BO MI / BREAD OF HEAVEN, ON THEE I FEED

13. OFFERTORY HYMNS Y 130, Y 549, E 769 (Tune: Spanish Chant) (Relief Fund) Y 130 1. B’ elese so ‘wo po, Ti nwon n’ de s’ Oluwa, Dimo si Kristi Re, Lati gan Oba na. B’ aiye sata Pelu Esu, Eke ni nwon Nwon nse lasan. 2. Olugbala, joba Lori oke Sion’; Ase ti Oluwa, Gbe Omo Tire ro: Lati ‘boji O ni, k’ O n’de, K’O si goke K’O gba ni la. 3. F’ eru sin Oluwa, Si bowo f’ ase Re; F’ ayo wa sodo Re; F’ iwariri duro; E kunle fun, K’e teriba, So t’ ipa Re; Ki Omo na. Y 549 1. Onje orun, ma bo mi, Ara Re l’ onje toto, Titi lai ni ngo ma je Onje oto at’ iye: Y’o si ma fun wa l’ okun Nipa emi Krist’ t’o ku. 2. Ajara orun, ‘bukun L’ ago t’ eje Re fun mi; Ogbe Re l’o wo mi san; Mo w’ agbelebu, mo ye, Iwo ti se iye mi, Jeki nma gbe inu Re. Amin. E 769 1. Bread of heaven, on Thee I feed, For Thy flesh is meat indeed: Ever may my soul be fed With this true and living bread; Day by day with strength supplied Through the life of Him who died. 2. Vine of heaven, Thy blood supplies This blest cup of sacrifice: ‘Tis Thy Cross I look and live: Thou my life, O let me be Rooted, grafted, built on Thee! Amen.

No comments:

Post a Comment

Roll Call of Members Alphabets T, W, X, Y & Z at 2024 Family Reunion Thanksgiving at Wesley Cathedral Olowogbowo

Alphabets T, W, X, Y, Z The N. A. B. Thomas Family The Adeoye Thomas Family The Kemi Thomas Family The Strack/Tay Family The B. K. Tandoh Fa...