Wednesday, May 6, 2020

E JE K'A JUMO F'OPE F'OLORUN

14. HOLY COMMUNION 15. PRAYER FOR THE CHILDREN AND THOSE PEOPLE THAT ARE YET TO BE CONFIRMED 16. LIFTING UP OF FAMILIES IN PRAYERS 17. NOTICES 18. GENERAL THANKSGIVING (ALL CARDED OFFERINGS) 19. EASTER THANKSGIVING 20. CLOSING HYMN : E je k’a jumo f’ ope f’ Olorun) (With Drum / Sunday Collection) 1. E je k’a jumo f’ope f’ Olorun Orin iyin at’ ope lo ye wa Iyanu n’ ife Re si gbogbo wa E korin ‘yin s’ oba Olore wa. Halleluya Ogo ni f’ Olorun A f’ ijo, ilu yin Olorun wa Alaye ni o yin O botiye Halleluya Ogo ni f’ Olorun. 2. Ki l’a fi san jawon ti ‘ku ti pa Iwo lo f’ owo wo wa di oni ‘Wo lo nso wa, t’o ngba wa low’ ewu E korin ‘yin s’ Olutoju wa. 3. Gbogbo alaye l’O nfun l’ onje won Iwo lo npese f’ onikaluku Iwo to sike eda Re gbogbo E korin ‘yin si Onibu-Ore. 4. Ohun wa ko dun to lati korin Enu wa ko gboro to fun ope B’ awa n’ egberun ahon nikokan Nwon kereju lati gbola Re ga. 5. Gbe wa leke ‘soro lojo gbogbo Fun wa l’ ayo at’ alafia Re Je k’a r’ ibukun gba lo ‘le wa K’a ba le wa f’ ogo f’ Oruko Re. 6. Eyin Angeli l’ orun wa ba wag be Orin iyin at’ ope lo ye wa S’ oba wa aiku Olola julo Oba wa Jehofa ti o j’ Oba.

No comments:

Post a Comment

Roll Call of Members Alphabets T, W, X, Y & Z at 2024 Family Reunion Thanksgiving at Wesley Cathedral Olowogbowo

Alphabets T, W, X, Y, Z The N. A. B. Thomas Family The Adeoye Thomas Family The Kemi Thomas Family The Strack/Tay Family The B. K. Tandoh Fa...