Saturday, December 28, 2024

Orin YMHB 88 - Ayo kun okan wa loni

13. ORIN YMHB 88 (AYO KUN OKAN WA LONI) 1. Ayo kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso ibi Re loni: E yo, Olorun d’ enia, O wa joko l’ aiye; Oruko wo l’o dun to ‘yi- Immanuel’. 2. A wole n’ ibuje eran, N’ iyanu l’a josin: Ibukun kan ko ta ‘yi yo, Ko s’ ayo bi eyi, E yo, Olorun, etc. 3. Aiye ko n’ adun fun wa mo, ‘Gbati a ba now O, L’ owo Wundia iya Re, ‘Wo Omo Iyanu. E yo, Olorun, etc. 4. Imole lat’ inu Imole Tan ‘mole s’ okun wa; K’a le ma fi isin mimo Se ‘ranti ojo Re. E yo, Olorun, etc.

No comments:

Post a Comment

Roll Call of Members Alphabets T, W, X, Y & Z at 2024 Family Reunion Thanksgiving at Wesley Cathedral Olowogbowo

Alphabets T, W, X, Y, Z The N. A. B. Thomas Family The Adeoye Thomas Family The Kemi Thomas Family The Strack/Tay Family The B. K. Tandoh Fa...